Marku 3:25 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní25 Bákan náà, bí ilé kan bá sì yapa sí ara rẹ, ilé náà kí yóò le è dúró. See the chapterYoruba Bible25 Bí àwọn ará ilé kan náà bá ń bá ara wọn jà, ilé náà kò lè fi ìdí múlẹ̀. See the chapterBibeli Mimọ25 Bi ile kan ba si yàpa si ara rẹ̀, ile na kì yio le duro. See the chapter |