Online Bible

- Advertisements -




Marku 3:18 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

18 Àti Anderu, Filipi, Bartolomeu, Matiu, Tomasi, Jakọbu ọmọ Alfeu, Taddeu, Simoni tí ń jẹ́ Sealoti (ọ̀kan nínú àwọn ẹgbẹ́ tí o ń ja fun òmìnira àwọn Júù).

See the chapter Copy

Yoruba Bible

18 ati Anderu, Filipi, Batolomiu, Matiu, ati Tomasi, Jakọbu ọmọ Alfeu, Tadiu, ati Simoni, ọmọ ẹgbẹ́ ìbílẹ̀ Kenaani,

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

18 Ati Anderu, ati Filippi, ati Bartolomeu, ati Matiu, ati Tomasi, ati Jakọbu ọmọ Alfeu, ati Taddeu, ati Simoni ti a npè ni Selote,

See the chapter Copy




Marku 3:18

Follow us:

Advertisements


Advertisements