Marku 2:28 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní28 Nítorí náà Ọmọ Ènìyàn ni Olúwa ọjọ́ ìsinmi pẹ̀lú.” See the chapterYoruba Bible28 Nítorí náà, Ọmọ-Eniyan ni Oluwa ohun gbogbo ati ti Ọjọ́ Ìsinmi pẹlu.” See the chapterBibeli Mimọ28 Nitorina Ọmọ-enia li oluwa ọjọ isimi pẹlu. See the chapter |