Johanu 2:24 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní24 Ṣùgbọ́n Jesu kò gbé ara lé wọn, nítorí tí ó mọ gbogbo ènìyàn. See the chapterYoruba Bible24 Ṣugbọn Jesu fúnrarẹ̀ kò gbára lé wọn, nítorí ó mọ gbogbo eniyan. See the chapterBibeli Mimọ24 Ṣugbọn Jesu kò gbé ara le wọn, nitoriti o mọ̀ gbogbo enia. See the chapter |