Joẹli 3:9 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní9 Ẹ kéde èyí ní àárín àwọn kèfèrí; Ẹ dira ogun, ẹ jí àwọn alágbára, Jẹ kí àwọn ajagun kí wọn bẹ̀rẹ̀ ogun, See the chapterYoruba Bible9 Ẹ kéde èyí láàrin gbogbo orílẹ̀-èdè. Ẹ múra ogun, ẹ rú àwọn akọni sókè. Kí gbogbo àwọn ọmọ ogun súnmọ́ tòsí, ogun yá! See the chapterBibeli Mimọ9 Ẹ kede eyi li ãrin awọn keferi; ẹ yà ogun si mimọ́, ẹ ji awọn alagbara, ẹ sunmọ tòsi, ẹ goke wá gbogbo ẹnyin ọkunrin ologun. See the chapter |