Joẹli 3:21 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní21 Nítorí èmi yóò wẹ ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ wọn nù, tí èmi kò tí ì wẹ̀nù. Nítorí Olúwa ń gbé Sioni.” See the chapterYoruba Bible21 N óo gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ àwọn tí ẹ pa, n kò sì ní dá ẹlẹ́bi sí, nítorí èmi OLUWA ni mò ń gbé Sioni.” See the chapterBibeli Mimọ21 Nitori emi o wẹ̀ ẹjẹ̀ wọn nù, ti emi kò ti wẹ̀nu: nitori Oluwa ngbe Sioni. See the chapter |