Joẹli 3:12 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 “Ẹ jí, ẹ sì gòkè wá sí Àfonífojì Jehoṣafati ẹ̀yin kèfèrí: nítorí níbẹ̀ ní èmi yóò jókòó láti ṣe ìdájọ́ àwọn kèfèrí yí káàkiri. See the chapterYoruba Bible12 Jẹ́ kí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè dìde, kí wọ́n wá sí àfonífojì Jehoṣafati, nítorí níbẹ̀ ni n óo ti ṣe ìdájọ́ gbogbo orílẹ̀-èdè tí ó wà ní àyíká. See the chapterBibeli Mimọ12 Ẹ ji, ẹ si goke wá si afonifojì Jehoṣafati ẹnyin keferi: nitori nibẹ̀ li emi o joko lati ṣe idajọ awọn keferi yikakiri. See the chapter |