Online Bible

- Advertisements -




Joẹli 3:11 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

11 Ẹ wá kánkán, gbogbo ẹ̀yin kèfèrí láti gbogbo àyíká, kí ẹ sì gbá ara yín jọ yí káàkiri. Níbẹ̀ ní kí o mú àwọn alágbára rẹ sọ̀kalẹ̀, Olúwa.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

11 Ẹ yára, ẹ wá, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè tí ẹ wà ní àyíká, ẹ parapọ̀ níbẹ̀. Rán àwọn ọmọ ogun rẹ wá, OLUWA.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

11 Ẹ kó ara nyin jọ, si wá, gbogbo ẹnyin keferi, ẹ si gbá ara nyin jọ yikakiri: nibẹ̀ ni ki o mu awọn alagbara rẹ sọkalẹ, Oluwa.

See the chapter Copy




Joẹli 3:11

Follow us:

Advertisements


Advertisements