Online Bible

- Advertisements -




Joẹli 3:1 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

1 “Ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì, àti ní àkókò náà, nígbà tí èmi tún mú ìgbèkùn Juda àti Jerusalẹmu padà bọ̀.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

1 “Wò ó! Nígbà tó bá yá, tí mo bá dá ire Juda ati ti Jerusalẹmu pada,

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

1 NITORINA kiyesi i, li ọjọ wọnni, ati li akokò na, nigbati emi o tun mu igbèkun Juda ati Jerusalemu padà bọ̀.

See the chapter Copy




Joẹli 3:1

Follow us:

Advertisements


Advertisements