Online Bible

- Advertisements -




Joẹli 2:8 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

8 Bẹ́ẹ̀ ni ẹnìkan kì yóò kọlu ẹnìkejì rẹ̀; olúkúlùkù wọn yóò rìn ní ọ̀nà rẹ̀: nígbà tí wọn bá sì ṣubú lù idà wọn kì yóò gbọgbẹ́.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

8 Wọn kò fi ara gbún ara wọn, olukuluku ń lọ ní ọ̀nà tirẹ̀; wọ́n kọlu àwọn nǹkan ààbò láìní ìdádúró.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

8 Bẹ̃ni ẹnikan kì yio tì ẹnikeji rẹ̀; olukuluku wọn o rìn li ọ̀na rẹ̀: nigbati nwọn ba si ṣubu lù idà, nwọn kì o gbọgbẹ́.

See the chapter Copy




Joẹli 2:8

Follow us:

Advertisements


Advertisements