Online Bible

- Advertisements -




Joẹli 2:7 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

7 Wọn yóò sáré bi àwọn alágbára; wọn yóò gùn odi bí ọkùnrin ológun; olúkúlùkù wọn yóò sì rìn lọ ní ọ̀nà rẹ̀, wọn kì yóò sì yà kúrò ni ọ̀nà wọn.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

7 Wọ́n ń sáré bí akọni, wọ́n ń fo ògiri bí ọmọ ogun. Wọ́n tò lọ́wọ̀ọ̀wọ́, ẹnikẹ́ni kò sì yà kúrò ní ọ̀nà tirẹ̀.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

7 Nwọn o sare bi awọn alagbara; nwọn o gùn odi bi ọkunrin ologun; olukuluku wọn o si rìn lọ li ọ̀na rẹ̀, nwọn kì yio si bà ọ̀wọ́ wọn jẹ.

See the chapter Copy




Joẹli 2:7

Follow us:

Advertisements


Advertisements