Online Bible

- Advertisements -




Joẹli 2:6 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

6 Ní ojú wọn, àwọn ènìyàn yóò jẹ ìrora púpọ̀: gbogbo ojú ní yóò ṣú dudu.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

6 Ìdààmú bá àwọn orílẹ̀-èdè tí ó bá ti fojú kàn wọ́n, gbogbo ọkàn á rẹ̀wẹ̀sì.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

6 Li oju wọn, awọn enia yio jẹ irora pupọ̀: gbogbo oju ni yio ṣú dùdu.

See the chapter Copy




Joẹli 2:6

Follow us:

Advertisements


Advertisements