Joẹli 2:24 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní24 Àwọn ilẹ̀ ìpakà yóò kún fún ọkà; àti ọpọ́n wọn nì yóò sàn jáde pẹ̀lú ọtí wáìnì tuntun àti òróró. See the chapterYoruba Bible24 Gbogbo ibi ìpakà ni yóo kún fún ọkà, ìkòkò waini ati ti òróró yín yóo kún àkúnwọ́sílẹ̀. See the chapterBibeli Mimọ24 Ati awọn ilẹ ipakà yio kún fun ọkà, ati ọpọ́n wọnni yio ṣàn jade pẹlu ọti-waini ati ororo. See the chapter |