Online Bible

- Advertisements -




Joẹli 2:18 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

18 Nígbà náà ní Olúwa yóò jowú fún ilẹ̀ rẹ̀, yóò sì káàánú fún ènìyàn rẹ̀.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

18 Nígbà náà ni ara bẹ̀rẹ̀ sí ta OLUWA nítorí ilẹ̀ rẹ̀, ó sì ṣàánú fún àwọn eniyan rẹ̀.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

18 Nigbana ni Oluwa yio jowú fun ilẹ rẹ̀, yio si kãnu fun enia rẹ̀.

See the chapter Copy




Joẹli 2:18

Follow us:

Advertisements


Advertisements