Online Bible

- Advertisements -




Esteri 3:10 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

10 Nítorí náà ọba sì bọ́ òrùka dídán (èdìdì) tí ó wà ní ìka rẹ̀ ó sì fi fún Hamani ọmọ Hammedata, ará Agagi, ọ̀tá àwọn Júù.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

10 Ọba bọ́ òrùka àṣẹ tí ó wà ní ọwọ́ rẹ̀, ó fún Hamani, ọmọ Hamedata, ará Agagi, ọ̀tá àwọn Juu.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

10 Ọba si bọ́ oruka rẹ̀ kuro li ọwọ rẹ̀, o si fi fun Hamani, ọmọ Medata, ara Agagi, ọta awọn Ju.

See the chapter Copy




Esteri 3:10

Follow us:

Advertisements


Advertisements