Online Bible

- Advertisements -




Esteri 1:9 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

9 Ayaba Faṣti náà ṣe àsè fún àwọn obìnrin ní ààfin ọba Ahaswerusi.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

9 Ayaba Faṣiti pàápàá se àsè fún àwọn obinrin ní ààfin ọba Ahasu-erusi.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

9 Faṣti ayaba sè àse pẹlu fun gbogbo awọn obinrin ni ile ọba ti iṣe ti Ahaswerusi.

See the chapter Copy




Esteri 1:9

Follow us:

Advertisements


Advertisements