Online Bible

- Advertisements -




Esteri 1:21 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

21 Ìmọ̀ràn yìí sì tẹ́ ọba àti àwọn ìjòyè rẹ̀ lọ́rùn, nítorí náà ọba ṣe gẹ́gẹ́ bí Memukani ṣé sọ.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

21 Inú ọba ati àwọn ìjòyè dùn sí ìmọ̀ràn yìí, nítorí náà ọba ṣe bí Memkani ti sọ.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

21 Ọ̀rọ na si dara loju ọba ati awọn ijoye; ọba si ṣe gẹgẹ bi ọ̀rọ Memukani:

See the chapter Copy




Esteri 1:21

Follow us:

Advertisements


Advertisements