Online Bible

- Advertisements -




Eksodu 6:5 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

5 Èmi sì ti tún gbọ́ kíkùn àwọn ọmọ Israẹli àwọn tí àwọn ará Ejibiti mú gẹ́gẹ́ bí ẹrú, àti pé èmi sì ti rántí májẹ̀mú Mi.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

5 Mo gbọ́ ìkérora àwọn ọmọ Israẹli tí àwọn ará Ijipti dì ní ìgbèkùn, mo sì ranti majẹmu mi.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

5 Emi si ti gbọ́ irora awọn ọmọ Israeli pẹlu, ti awọn ara Egipti nmu sìn; emi si ti ranti majẹmu mi.

See the chapter Copy




Eksodu 6:5

Follow us:

Advertisements


Advertisements