Eksodu 6:17 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní17 Àwọn ọmọ Gerṣoni ni ìran wọn ni: Libni àti Ṣimei. See the chapterYoruba Bible17 Geriṣoni bí ọmọ meji: Libini ati Ṣimei, wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé wọn. See the chapterBibeli Mimọ17 Awọn ọmọ Gerṣoni; Libni, ati Ṣimei, ni idile wọn. See the chapter |