Online Bible

- Advertisements -




Eksodu 5:13 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

13 Àwọn akóniṣiṣẹ́ sì ń ni wọ́n lára, wọ́n wí pé, “Ẹ parí iṣẹ́ tí ẹ ni láti ṣe fún ọjọ́ kan bí ìgbà ti a ń fún un yin ní koríko gbígbẹ.”

See the chapter Copy

Yoruba Bible

13 Àwọn tí wọn ń kó wọn ṣiṣẹ́ a máa fi ipá mú wọn pé, lojumọ, wọ́n gbọdọ̀ mọ iye bíríkì tí wọ́n máa ń mọ tẹ́lẹ̀, nígbà tí wọn kò tíì máa wá koríko fúnra wọn.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

13 Awọn akoniṣiṣẹ lé wọn ni ire wipe, Ẹ ṣe iṣẹ nyin pé, iṣẹ ojojumọ́ nyin, bi igbati koriko mbẹ.

See the chapter Copy




Eksodu 5:13

Follow us:

Advertisements


Advertisements