Eksodu 5:12 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní12 Gbogbo wọn sí fọ́n káàkiri ni ilẹ̀ Ejibiti láti sa ìdì koríko tí wọn yóò lò bí ì koríko gbígbẹ fún sísun bíríkì. See the chapterYoruba Bible12 Wọ́n bá fọ́n káàkiri gbogbo ilẹ̀ Ijipti láti wá àgékù koríko. See the chapterBibeli Mimọ12 Bẹ̃li awọn enia na si tuka kiri ká gbogbo ilẹ Egipti lati ma ṣà idi koriko ni ipò koriko. See the chapter |