Eksodu 4:29 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní29 Mose àti Aaroni pe gbogbo àwọn àgbàgbà Israẹli jọ. See the chapterYoruba Bible29 Mose ati Aaroni bá lọ sí Ijipti, wọ́n kó gbogbo àgbààgbà àwọn eniyan Israẹli jọ. See the chapterBibeli Mimọ29 Mose ati Aaroni si lọ, nwọn si kó gbogbo àgba awọn ọmọ Israeli jọ: See the chapter |