Online Bible

- Advertisements -




Eksodu 4:28 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

28 Ní ìgbà náà ni Mose sì sọ ohun gbogbo tí Ọlọ́run ti rán fún Aaroni àti nípa gbogbo iṣẹ́ ìyanu tí Ọlọ́run ti pàṣẹ fún un láti ṣe ní iwájú Farao.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

28 Mose sọ gbogbo iṣẹ́ tí OLUWA rán an fún un, ati gbogbo iṣẹ́ ìyanu tí OLUWA pa láṣẹ pé kí ó ṣe.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

28 Mose si sọ gbogbo ọ̀rọ OLUWA ti o rán a fun Aaroni, ati gbogbo aṣẹ iṣẹ-àmi ti o fi fun u.

See the chapter Copy




Eksodu 4:28

Follow us:

Advertisements


Advertisements