Online Bible

- Advertisements -




Eksodu 3:4 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

4 Nígbà tí Olúwa rí i pe Mose ti lọ láti lọ wò ó, Ọlọ́run ké pè é láti àárín igbó náà, “Mose! Mose!” Mose sì dáhùn ó wí pé, “Èmi nìyìí.”

See the chapter Copy

Yoruba Bible

4 Nígbà tí Ọlọrun rí i pé ó súnmọ́ ọn láti wo ohun ìyanu náà, Ọlọrun pè é láti inú igbó náà, ó ní, “Mose! Mose!” Mose dáhùn pé, “Èmi nìyí.”

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

4 Nigbati OLUWA ri pe, o yipada si apakan lati wò o, Ọlọrun kọ si i lati inu ãrin igbẹ́ na wá, o si wipe, Mose, Mose. On si dahun pe, Emi niyi.

See the chapter Copy




Eksodu 3:4

Follow us:

Advertisements


Advertisements