Online Bible

- Advertisements -




Eksodu 2:25 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

25 Nítorí náà, Ọlọ́run bojú wo àwọn ará Israẹli, Ó sì wà láti gbà wọ́n sílẹ̀.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

25 Ọlọrun bojú wo àwọn eniyan Israẹli, ó sì rí irú ipò tí wọ́n wà.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

25 Ọlọrun si bojuwò awọn ọmọ Israeli, Ọlọrun si mọ̀ ọ fun wọn.

See the chapter Copy




Eksodu 2:25

Follow us:

Advertisements


Advertisements