Online Bible

- Advertisements -




Eksodu 1:5 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

5 Àwọn ìran Jakọbu sì jẹ́ àádọ́rin ní àpapọ̀; Josẹfu sì ti wà ní Ejibiti.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

5 Gbogbo àwọn ọmọ ati àwọn ọmọ ọmọ Jakọbu jẹ́ aadọrin, Josẹfu ti wà ní Ijipti ní tirẹ̀.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

5 Ati gbogbo ọkàn ti o ti inu Jakobu jade, o jẹ́ ãdọrin ọkàn: Josefu sa ti wà ni Egipti.

See the chapter Copy




Eksodu 1:5

Follow us:

Advertisements


Advertisements