Eksodu 1:13 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní13 Àwọn ará Ejibiti sì mú àwọn ọmọ Israẹli sìn ní àsìnpa. See the chapterYoruba Bible13 Nítorí náà, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí fi iṣẹ́ àṣekára ni àwọn ọmọ Israẹli lára, See the chapterBibeli Mimọ13 Awọn ara Egipti si mu awọn ọmọ Israeli sìn li asìnpa: See the chapter |