Online Bible

- Advertisements -




Efesu 2:21 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

21 Nínú rẹ ni gbogbo ilé náà, tí a ń kọ wà papọ̀ ṣọ̀kan tí ó sì ń dàgbàsókè láti di tẹmpili mímọ́ kan nínú Olúwa:

See the chapter Copy

Yoruba Bible

21 Òun ni ó mú kí gbogbo ilé dúró dáradára, tí ó sì mú un dàgbà láti di ilé ìsìn mímọ́ fún Oluwa.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

21 Ninu ẹniti gbogbo ile na, ti a nkọ ṣọkan pọ, ndagbà soke ni tẹmpili mimọ́ ninu Oluwa:

See the chapter Copy




Efesu 2:21

Follow us:

Advertisements


Advertisements