Online Bible

- Advertisements -




Daniẹli 5:31 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

31 Dariusi ará Media sì gba ìjọba nígbà tí ó di ọmọ ọdún méjìlélọ́gọ́ta.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

31 Dariusi, ará Mede, ẹni ọdún mejilelọgọta sì jọba lẹ́yìn rẹ̀.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

31 Dariusi, ara Media si gba ijọba na, o si jẹ bi ẹni iwọn ọdun mejilelọgọta.

See the chapter Copy




Daniẹli 5:31

Follow us:

Advertisements


Advertisements