Online Bible

- Advertisements -




Daniẹli 5:26 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

26 “Èyí ni nǹkan tí ọ̀rọ̀ náà túmọ̀ sí: “Mene: Ọlọ́run ti ṣírò ọjọ́ ìjọba rẹ. Ó sì ti mú u wá sí òpin.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

26 Ìtumọ̀ rẹ̀ sì nìyí: MENE, Ọlọrun ti ṣírò àwọn ọjọ́ ìjọba rẹ, ó sì ti parí rẹ̀.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

26 Eyi ni itumọ ohun na: MENE, Ọlọrun ti ṣirò ijọba rẹ, o si pari rẹ̀.

See the chapter Copy




Daniẹli 5:26

Follow us:

Advertisements


Advertisements