Daniẹli 5:24 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní24 Nítorí náà, ó rán ọwọ́ tí ó kọ àkọlé yìí. See the chapterYoruba Bible24 Ìdí nìyí tí ó fi rán ọwọ́ kan jáde láti kọ àkọsílẹ̀ yìí. See the chapterBibeli Mimọ24 Nitorina ni a ṣe rán ọwọ na lati ọdọ rẹ̀ wá; ti a si fi kọ iwe yi. See the chapter |