Online Bible

- Advertisements -




Daniẹli 4:13 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

13 “Lórí ibùsùn mi, mo rí ìran náà, olùṣọ́ kan dúró síwájú u mi, àní ẹni mímọ́ kan, ó ń bọ̀ wá láti ọ̀run

See the chapter Copy

Yoruba Bible

13 “Ní ojúran, lórí ibùsùn mi, mo rí olùṣọ́ kan, Ẹni Mímọ́,

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

13 Mo ri ninu iran ori mi lori akete mi, si kiye si i, oluṣọ, ani ẹni mimọ́ kan sọkalẹ lati ọrun wá;

See the chapter Copy




Daniẹli 4:13

Follow us:

Advertisements


Advertisements