Online Bible

- Advertisements -




Daniẹli 3:8 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

8 Ní àsìkò yìí ni àwọn awòràwọ̀ bọ́ síwájú, wọ́n sì fi ẹ̀sùn kan àwọn ará Juda.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

8 Àwọn ará Kalidea kan wá siwaju ọba, wọ́n fi ẹ̀sùn kan àwọn Juu pẹlu ìríra, wọ́n ní,

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

8 Lakokò na ni awọn ọkunrin ara Kaldea kan wá, nwọn si fi awọn ara Juda sùn.

See the chapter Copy




Daniẹli 3:8

Follow us:

Advertisements


Advertisements