Online Bible

- Advertisements -




Daniẹli 3:20 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

20 ó sì pàṣẹ fún àwọn alágbára nínú ogun rẹ̀ pé, kí wọ́n de Ṣadraki, Meṣaki àti Abednego, kí wọn sì jù wọ́n sínú iná ìléru.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

20 Ó tún pàṣẹ pé kí àwọn akọni ninu àwọn ọmọ ogun rẹ̀ di Ṣadiraki, Meṣaki ati Abedinego, kí wọ́n sì sọ wọ́n sinu adágún iná.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

20 O si paṣẹ fun awọn ọkunrin ani awọn alagbara julọ ninu ogun rẹ̀ pe ki nwọn ki o di Ṣadraki, Meṣaki, ati Abednego, ki nwọn ki o si sọ wọn sinu iná ileru na ti njo.

See the chapter Copy




Daniẹli 3:20

Follow us:

Advertisements


Advertisements