Online Bible

- Advertisements -




Daniẹli 3:16 - Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

16 Ṣadraki, Meṣaki àti Abednego dá ọba lóhùn wí pé, “Nebukadnessari, kì í ṣe fún wa láti gba ara wa sílẹ̀ níwájú u rẹ nítorí ọ̀rọ̀ yìí.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

16 Ṣadiraki, Meṣaki ati Abedinego dá ọba lóhùn pé, “Kabiyesi, kò yẹ kí á máa bá ọ jiyàn lórí ọ̀rọ̀ yìí.

See the chapter Copy

Bibeli Mimọ

16 Ṣadraki, Meṣaki, ati Abednego dahùn, nwọn si wi fun ọba pe, Nebukadnessari, kò tọ si wa lati fi èsi kan fun ọ nitori ọ̀ran yi.

See the chapter Copy




Daniẹli 3:16

Follow us:

Advertisements


Advertisements