Numeri 4:48 - Bibeli Mimọ48 Ani awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgbẹtalelẹgbarin o din ogun. See the chapterYoruba Bible48 jẹ́ ẹgbaarin ó lé ẹgbẹta ó dín ogún (8,580). See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní48 Àpapọ̀ iye wọn jẹ́ ẹgbẹ̀tàlá lé lẹ́gbàarin ó dín ogún (8,580). See the chapter |