Numeri 3:29 - Bibeli Mimọ29 Awọn idile ti awọn ọmọ Kohati ni ki o pagọ́ lẹba agọ́ si ìha gusù. See the chapterYoruba Bible29 Àwọn ọmọ Kohati yóo pàgọ́ tiwọn sí ẹ̀gbẹ́ Àgọ́ Àjọ ní ìhà gúsù. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní29 Àwọn ìdílé Kohati yóò pa ibùdó wọn sí ìhà gúúsù ní ẹ̀gbẹ́ àgọ́. See the chapter |