Online Bible

- Advertisements -




Numeri 2:30 - Bibeli Mimọ

30 Ati ogun rẹ̀, ati awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgba mẹrindilọgbọ̀n o le egbeje.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

30 Àwọn ọmọ ogun rẹ̀ tí a kà jẹ́ ọ̀kẹ́ meji ó lé ẹẹdẹgbaaje ati irinwo (53,400).

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

30 Iye ìpín rẹ̀ jẹ́ ẹgbàá-mẹ́rìn-dínlógún ó-lé-egbèje (53,400).

See the chapter Copy




Numeri 2:30

Follow us:

Advertisements


Advertisements