Numeri 2:23 - Bibeli Mimọ23 Ati ogun rẹ̀, ati awọn ti a kà ninu wọn, jẹ́ ẹgba mẹtadilogun o le egbeje. See the chapterYoruba Bible23 Àwọn ọmọ ogun rẹ̀ tí a kà jẹ́ ẹgbaa mẹtadinlogun ó lé egbeje (35,400). See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní23 Iye ìpín rẹ̀ ni ẹgbàá-mẹ́tà-dínlógún ó-lé-egbèje (35,400). See the chapter |