Numeri 1:47 - Bibeli Mimọ47 Ṣugbọn awọn ọmọ Lefi gẹgẹ bi ẹ̀ya baba wọn li a kò kà mọ́ wọn. See the chapterYoruba Bible47 Ṣugbọn wọn kò ka àwọn ọmọ Lefi mọ́ wọn, See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní47 A kò ka àwọn ìdílé ẹ̀yà Lefi mọ́ àwọn ìyókù. See the chapter |