Numeri 1:17 - Bibeli Mimọ17 Ati Mose ati Aaroni mú awọn ọkunrin wọnyi ti a pè li orukọ: See the chapterYoruba Bible17 Mose ati Aaroni pe gbogbo àwọn ọmọ Israẹli jọ ní ọjọ́ kinni oṣù keji, See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní17 Mose àti Aaroni mú àwọn ènìyàn tí a dárúkọ wọ̀nyí See the chapter |