Online Bible

- Advertisements -




Matiu 2:3 - Bibeli Mimọ

3 Nigbati Herodu ọba si gbọ́, ara rẹ̀ kò lelẹ, ati gbogbo awọn ará Jerusalemu pẹlu rẹ̀.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

3 Nígbà tí Hẹrọdu gbọ́, ara rẹ̀ kò balẹ̀, ara gbogbo eniyan ìlú Jerusalẹmu náà kò sì balẹ̀.

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

3 Nígbà tí ọba Herodu sì gbọ́ èyí, ìdààmú bá a àti gbogbo àwọn ara Jerusalẹmu pẹ̀lú rẹ̀

See the chapter Copy




Matiu 2:3

Follow us:

Advertisements


Advertisements