Online Bible

- Advertisements -




Matiu 2:20 - Bibeli Mimọ

20 Wipe, Dide, mu ọmọ-ọwọ na, ati iya rẹ̀, ki o si lọ si ilẹ Israeli: nitori awọn ti nwá ẹmí ọmọ-ọwọ na lati pa ti kú.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

20 Ó sọ fún un pé, “Dìde, gbé ọmọ náà ati ìyá rẹ́, kí o pada lọ sí ilẹ̀ Israẹli, nítorí àwọn tí wọ́n fẹ́ pa ọmọ náà ti kú.”

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

20 Ó sì wí fún un pé, “Dìde gbé ọmọ ọwọ́ náà àti ìyá rẹ̀ padà sí ilẹ̀ Israẹli, nítorí àwọn tí ń wá ẹ̀mí ọmọ ọwọ́ náà láti pa ti kú.”

See the chapter Copy




Matiu 2:20

Follow us:

Advertisements


Advertisements