Matiu 2:14 - Bibeli Mimọ14 Nigbati o si dide, o mu ọmọ-ọwọ na ati iya rẹ̀ li oru, o si lọ si Egipti; See the chapterYoruba Bible14 Josẹfu bá dìde ní òru, ó gbé ọmọ náà ati ìyá rẹ̀, ó lọ sí Ijipti. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní14 Nígbà náà ni ó sì dìde, ó mú ọmọ ọwọ́ náà àti ìyá rẹ̀ ní òru, ó sì lọ sí Ejibiti, See the chapter |