Matiu 2:10 - Bibeli Mimọ10 Nigbati nwọn si ri irawọ na, nwọn yọ̀ ayọ nlanla. See the chapterYoruba Bible10 Nígbà tí wọ́n rí ìràwọ̀ náà, inú wọn dùn gan-an. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní10 Nígbà tí wọ́n sì rí ìràwọ̀ náà, ayọ̀ kún ọkàn wọn. See the chapter |