Online Bible

- Advertisements -




Marku 6:55 - Bibeli Mimọ

55 Nwọn si sare lọ si gbogbo igberiko yiká, nwọn bẹ̀rẹ si ima gbé awọn ti ara wọn ṣe alaida wá lori akete, si ibiti nwọn gbọ́ pe o wà.

See the chapter Copy

Yoruba Bible

55 Wọ́n bá ń súré láti gbogbo àdúgbò ibẹ̀, wọ́n ń gbé àwọn aláìsàn wọn lórí ibùsùn wá sí ibikíbi tí wọn bá gbọ́ pé Jesu wà.

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

55 Wéré, wọ́n ròyìn dídé rẹ̀, gbogbo àwọn ènìyàn sáré gbé gbogbo àwọn aláìsàn lórí àkéte wọn wá pàdé rẹ̀.

See the chapter Copy




Marku 6:55

Follow us:

Advertisements


Advertisements