Marku 3:25 - Bibeli Mimọ25 Bi ile kan ba si yàpa si ara rẹ̀, ile na kì yio le duro. See the chapterYoruba Bible25 Bí àwọn ará ilé kan náà bá ń bá ara wọn jà, ilé náà kò lè fi ìdí múlẹ̀. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní25 Bákan náà, bí ilé kan bá sì yapa sí ara rẹ, ilé náà kí yóò le è dúró. See the chapter |