Marku 3:15 - Bibeli Mimọ15 Ati lati li agbara lati wò arunkarun san, ati lati lé awọn ẹmi èṣu jade: See the chapterYoruba Bible15 kí wọn lè ní àṣẹ láti máa lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní15 àti láti lágbára láti lé àwọn ẹ̀mí Èṣù jáde. See the chapter |