Online Bible

- Advertisements -




Marku 2:27 - Bibeli Mimọ

27 O si wi fun wọn pe, A dá ọjọ isimi nitori enia, a kò dá enia nitori ọjọ isimi:

See the chapter Copy

Yoruba Bible

27 Ó wá wí fún wọn pé, “Lílò eniyan ni a dá Ọjọ́ Ìsinmi fún, a kò dá eniyan fún Ọjọ́ Ìsinmi.

See the chapter Copy

Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní

27 Ó sì wí fún wọ́n pé, a dá ọjọ́ ìsinmi fún ènìyàn, “Ṣùgbọ́n a kò dá ènìyàn fún ọjọ́ ìsinmi.

See the chapter Copy




Marku 2:27

Follow us:

Advertisements


Advertisements