Johanu 2:2 - Bibeli Mimọ2 A si pè Jesu ati awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ pẹlu, si ibi igbeyawo. See the chapterYoruba Bible2 Wọ́n pe Jesu ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sí ibi igbeyawo náà. See the chapterBíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní2 A sì pe Jesu àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sí ibi ìgbéyàwó náà. See the chapter |